JSS 2 YORUBA Scheme of Work | 1st, 2nd & 3rd Term

Share the News!

The Yoruba language scheme of work for JSS 2 is designed to build your skills in both oral and written Yoruba, ensuring a comprehensive grasp of the language. 

This article walks you through the curriculum, week by week, and provides a list of recommended textbooks that align with the topics covered. 

It’s an essential resource to help you stay on course throughout the academic year. 

Let this article be your guide to excelling in Yoruba language studies this term.

JSS 2 YORUBA Scheme of Work

JSS 2 YORUBA First Term Scheme of Work

Week 1: Àmì ohùn

  • Àmì ohùn Yorùbá mẹ́tẹ́ẹ̀ta(\- /) ìsàlẹ̀, àárín àti òkè

Week 2: Àṣà Ìgbéyàwó

  • Ìtumọ̀, ìlànà àṣà ìgbéyàwó ìbílẹ̀, ìgbéyàwó ìbílẹ̀ àti ti òde òní
  • Ewu inú ìbálòpọ̀ ṣáájú ìgbéyàwó

Week 3: Òǹkà Èdè Yorùbá

  • Òǹkà Ẹgbẹ̀rún dé Ẹgbẹ̀rúnméjì (1000-2000)
  • Ìgbésẹ̀ àti bí a ṣe ń ka Òǹkà

Week 4: Ìsọ̀rí Ọ̀rọ̀ Yorùbá

  • Ọ̀rọ̀ Orúkọ, Arọ́pò Orúkọ, Ọ̀rọ̀ Ìṣe,Ọ̀rọ̀ Àpèjúwe, Ọ̀rọ̀ Atọ́kùn àti

Week 5: Ọ̀rọ̀ Àsopọ̀.

Week 6: Àsàyàn Ìwé kíkà-Eré oníṣe

Week 7: Ìhun Ọ̀rọ̀ àti Ìtumọ̀

  • Oríṣìíriṣìí Ìhun Ọ̀rọ̀ f (o, a, e) kf (wá, lọ, jẹ) fkf (ẹja, omi, ìlú, ọjà)

Week 8: Àsàyàn Ìwé Àyọkà (Ewì)

Week 9: Oríṣìíriṣi Gbólóhùn

  • Ìtumọ̀ àti Àpẹẹrẹ
  • Gbólóhùn Alábọ̀dè, Alákànpọ̀ àti Oníbọ 

Week 10: Àsàyàn Ìwé Àyọkà (Ewì)

Week 11: Àtúnyẹ̀wò Iṣẹ́ Sáà kì-ín-ní

Week 12: Ìdánwò àti Mímáàkì Ìdánwò

Week 13: Èsì Ìdánwò àti Ìsinmi 

JSS 2 YORUBA Second Term Scheme of Work

Week 1: Àsàyàn Ìwé Àyọkà – Ìtàn Àròṣọ [Ọlọ́rọ̀geere]

Week 2: Ẹ̀sìn ìbílẹ̀

  • Ìtumọ̀, Ipa Ẹ̀sìn Láwùjọ

Week 3: Ìtẹ̀síwájú lórí Àkàyé

Week 4: Orin

  • Kíkọ orin ìbílẹ̀ – orin/ìbílẹ̀ níbi Ìgbéyàwó, Erémọdé,Oyè jíjẹ, ìkómọjáde àti Ẹ̀kọ́ ìwàrere.

Week 5: Ìsáré (Ajẹmẹ́sìn àti Ajẹmọ́ayẹyẹ)

  • Ìtumọ̀ àti àpẹẹrẹ (Ìwì Egúngún/Ẹ̀sà, Ìyẹ̀rẹ̀ Ifá, Ìjálá, Ṣàngó pípe, Èṣù pípe, Rárà, Ẹkún Ìyàwó, Ègé, Alámọ̀ (abbl)

Week 6: Ogun àti Àlááfíà

  • Ogun ní ilẹ̀ Yorùbá látijọ àti àpẹẹrẹ. Jálumi,Kírìjí, Mogbàmogbà (abbl)
  • Àǹfààní àti Àléébù Ogun jíjà
  • Ọ̀nà láti dẹ́kun Ogun/wá Àlááfíà

Week 7: Mid-Term Break

Week 8: Ewì Alohùn-Àrángbọ́

  • Ìtumọ̀ àti Àpẹẹrẹ-Oríkì, Ẹsẹ Ifá, Ọfọ̀
  • Àrángbọ́ kíkún àti kéékèèkéé. Òwe, Àlọ́ Àpamọ̀, Àrọ̀.

Week 9: Àṣà Ìsọmọlórúkọ nílẹ̀ Yorùbá

  • Ètò Ìsọmọlórúkọ àti Ohun Èlò

Week 10: Ìlànà Ìsọmọlórúkọ – Ìgbésẹ̀ ní ṣíṣẹ̀-n-tẹ̀lé 

Week 11: Àtúnyẹ̀wò Iṣẹ́ Sáà kejì

Week 12: Ìdánwò/Mímáàkì

Week 13: Èsì Ìdánwò àti Ìsinmi 

JSS 2 YORUBA Third Term Scheme of Work

Week 1: Àròkọ –‘Ilé Ìwé Mi’

Week 2: Ìwé kíkà-‘Subúseré – láti ọwọ́ Lásúnkànmí Tẹ̀là

Week 3: Àṣà Ìranra-Ẹni-lọ́wọ́

  • -Ìtumọ̀ àti àpẹẹrẹ- Èsúsú, Àjọ, Òwe, Àáró, Àrokodóko
  • Pàtàkì Àṣà Ìranra-Ẹni-lọ́wọ́

Week 4: Lẹ́tà kíkọ-Àìgbagbẹ̀fẹ́

  • Ìlànà kíkọ lẹ́tà

Week 5: Ewì Àyọkà- Ìjìnlẹ̀ Àròfọ̀ Yorùbá Mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n – láti ọwọ́ Kọ́lá Àjíbádé

Week 6: Ìwé kíkà-‘Subúseré’- Lásúnkànmí Tẹ̀là.

Week 7: Mid-Term Break

Week 8: Ẹ̀yà Gbólóhùn Yorùbá

Week 9: Ìtẹ̀síwájú Àkàyé

Week 10: Àrọ̀kọ- ‘Bí mo ṣe lo Ìsinmi tó kọjá’ 

Week 11: Àtúnyẹ̀wò Iṣẹ́ Sáà kejì

Week 12: Ìdánwò/Mímáàkì

Week 13: Èsì Ìdánwò àti Ìsinmi

JSS 2 YORUBA Recommended Textbook

  1. Ede Yoruba Lákọ̀ọ́kàn by Adebisi A. Bello
  2. Iwe Asa ati Litireso Yoruba by Akinola A.

RECAP

This article details the scheme of work for Yoruba Language in JSS 2, including essential topics like Yoruba phonetics, sentence construction, proverbs, and traditional literature. 

Over the course of the three terms, you also study key cultural practices and idiomatic expressions. 

The recommended textbooks are listed to provide additional support in mastering the language. 

This guide ensures a well-rounded approach to Yoruba language and culture for the full academic session.

DISCLAIMER: Everything on this page is based on our research of what is obtainable for schools in all the states in the country, including government and some private schools. Schemes of work normally undergo a series of reviews and some schools modify them to suit their specific needs. 

While we do all our possible best to keep up with the latest and approved schemes of work in the country, check the specific template your school uses. For example, some private secondary schools integrate the British curriculum. If you teach in such schools, expect to see slight changes to what we offer on this page. If you have any questions or require personalised support, kindly feel free to contact us.

Share the News!

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top